
Oluwaetobi
oluwaetobi
E kaaroo gbogbo èniyàn, emi ni Kristeni ati mo wa lati Nigeria, mo wa lati ilè Yoruba. Mi o siseto dada, sùgbon ma da, mo sise lori ejo mi ati mo nireti pé ni ojo kan, ko ma si èniyàn ti o le segun ejo mi. Olorun ni fun yin ibukun.
Joined Apr 11, 2025
6,081
Global Rating
Battlesnakes
Ogbon ( Always active )
Ejo yii je lowo ni gbogbo asiko ati e le seré pelu o ni gbogbo asiko
Ogbon ( Rarely active )
ole ni ejo yii, e ko le seré pelu o ni gbogbo asiko, asiko ti e le seré pelu o kékeré
Saved Games
ere adashe ti o dara gidigan awon gbékuro ti o tobi ju edegberin
Standard mode, standard map, 1 Battlesnakes, 11x11 Board, 764 Turns
ere mi dara gidigan, gbékuro ti o poju irinwo (400)
Standard mode, standard map, 4 Battlesnakes, 11x11 Board, 446 Turns
Mo ti sere pelu Poc ati Smarty Rat!!!!
Standard mode, royale map, 4 Battlesnakes, 11x11 Board, 272 Turns
ere yi lo daa ju gidigan
Standard mode, standard map, 4 Battlesnakes, 11x11 Board, 1000 Turns
ere yi gun gidigan
Standard mode, standard map, 4 Battlesnakes, 11x11 Board, 918 Turns
Ere ti o gùn gidigan, pelu «smartyRat, Poc, SpaceHeater» ati miiran
Standard mode, standard map, 4 Battlesnakes, 11x11 Board, 826 Turns